Nọ́ḿbà 16:38 BMY

38 Èyí ni àwo tùràrí àwọn tí ó kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Kí ẹ gún àwo tùràrí yìí, kí ẹ sì fi ṣe ìbòrí fún pẹpẹ, wọ́n jẹ́ mímọ́ nítorí pé wọ́n ti mú wọn wá ṣíwájú Olúwa. Kí wọ́n jẹ́ àmì fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:38 ni o tọ