Nọ́ḿbà 16:39 BMY

39 Élíásárì tí í ṣe àlùfáà sì kó gbogbo àwo tùràrí tí àwọn tí ó jóná mú wa, ó gún wọn pọ̀, ó fi ṣe ìbòrí fún pẹpẹ,

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:39 ni o tọ