Nọ́ḿbà 16:40 BMY

40 Gẹ́gẹ́ bí Olúwa ṣe sọ láti ẹnu Mósè. Èyí yóò jẹ́ ohun ìrántí fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ẹlòmíràn yàtọ̀ sí irú ọmọ Árónì kò gbọdọ̀ jó tùràrí níwájú Olúwa, ẹni tí ó bá ṣe bẹ́ẹ̀, yóò dàbí Kórà àti àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:40 ni o tọ