Nọ́ḿbà 16:46 BMY

46 Mósè sì sọ fún Árónì pé, “Mú àwo tùràrí, kí o fi iná sí i lórí pẹpẹ, fi tùràrí sínú rẹ̀, kí o sì tètè mu lọ sí àárin ìjọ ènìyàn láti ṣètùtù fún wọn nítorí pé ìbínú Olúwa ti jáde, àjàkálẹ̀-àrùn sì ti bẹ̀rẹ̀.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:46 ni o tọ