Nọ́ḿbà 16:47 BMY

47 Árónì ṣe bí Mósè ti wí, ó sáré lọ sí àárin àwọn ènìyàn, ṣùgbọ́n àjàkálẹ̀-àrùn ti bẹ̀rẹ̀ láàrin wọn, ṣùgbọ́n Árónì fín tùràrí, ó sì ṣe ètùtù fún wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:47 ni o tọ