Nọ́ḿbà 2:31 BMY

31 Gbogbo ènìyàn tí a yàn sí ibùdó Dánì jẹ́ ẹgbàá méjìdínlọ́gọ̀rún-ó-lé-ẹgbẹ̀jọ (157,600). Àwọn ni yóò jáde kẹ́yìn lábẹ́ ọ̀págun wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 2

Wo Nọ́ḿbà 2:31 ni o tọ