Nọ́ḿbà 2:32 BMY

32 Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tí wọ́n kà nípa ìdílé wọn. Gbogbo àwọn tó wà ní ibùdó, gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn, wọ́n jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́-ó-lé-egbéjìdínlógún-dín àádọ́ta (603,550).

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 2

Wo Nọ́ḿbà 2:32 ni o tọ