Nọ́ḿbà 20:10 BMY

10 Òun àti Árónì pe àwọn ènìyàn jọ sí ojú kan níwájú àpáta, Mósè sì sọ fún wọn, “Ẹ gbọ́, ẹ̀yín ọlọ̀tẹ̀, àwa kì yóò lè mú omi jáde láti inú àpáta yìí wá bí?”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 20

Wo Nọ́ḿbà 20:10 ni o tọ