Nọ́ḿbà 20:11 BMY

11 Nígbà náà ni Mósè gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè ó sì fi ọ̀pá ọwọ́ rẹ̀ lu àpáta lẹ́ẹ̀méjì. Omi sì tú jáde, gbogbo ìjọ ènìyàn àti àwọn ẹran ọ̀sìn wọn sì mu.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 20

Wo Nọ́ḿbà 20:11 ni o tọ