Nọ́ḿbà 20:14 BMY

14 Mósè sì ránṣẹ́ láti Kádésì sí ọba Édómù, wí pé:“Èyí ni nǹkan tí arákùnrin rẹ Ísírẹ́lì sọ: Ìwọ ti mọ̀ nípa gbogbo ìnira, tí ó wá sí orí wa.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 20

Wo Nọ́ḿbà 20:14 ni o tọ