Nọ́ḿbà 21:1 BMY

1 Nígbà tí ọba Árádì ará Kénánì, tí ń gbé ní Gúúsù gbọ́ wí pé Ísírẹ́lì ń bọ̀ wá ní ojú ọ̀nà Átarímù, ó bá Ísírẹ́lì jà ó sì fi agbára mú díẹ̀ lára wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 21

Wo Nọ́ḿbà 21:1 ni o tọ