Nọ́ḿbà 21:2 BMY

2 Nígbà náà ni Ísírẹ́lì jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Olúwa pé: “Bí o bá lè fi àwọn ènìyàn yìí lé wa lọ́wọ́, gbogbo ìlú wọn ni a ó pa run.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 21

Wo Nọ́ḿbà 21:2 ni o tọ