Nọ́ḿbà 21:3 BMY

3 Olúwa gbọ́ ẹ̀bẹ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ó sì fi àwọn ará Kénánì lé wọn lọ́wọ́. Wọ́n pa wọ́n run pátapáta; torí náà ni a ṣe ń pe ibẹ̀ ní Hómà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 21

Wo Nọ́ḿbà 21:3 ni o tọ