Nọ́ḿbà 21:32 BMY

32 Lẹ́yìn ìgbà tí Mósè rán wọn lọ sí Jésírélì, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì gba àwọn agbégbé tó yí wọn ká wọ́n sì lé àwọn Ámórì tó wà níbẹ̀ jáde.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 21

Wo Nọ́ḿbà 21:32 ni o tọ