33 Nígbà náà wọ́n pẹ̀yìn dà wọ́n sì gòkè lọ sí Básánì, Ógì ọba ti Básánì àti gbogbo àwọn ọmọ ogun tí ó wọ́de ogun jáde lati pàdé wọn ní ojú ogun ní Édírélì.
Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 21
Wo Nọ́ḿbà 21:33 ni o tọ