Nọ́ḿbà 23:19 BMY

19 Ọlọ́run kì í ṣe ènìyàn, tí yóò fi purọ́,tàbí ọmọ ènìyàn, tí ó lè yí ọkàn rẹ̀ padà.Ǹjẹ́ ó sọ̀rọ̀ kí ó má ṣe é?Ǹjẹ́ ó ti ṣèlérí kí ó má mu-un ṣẹ?

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 23

Wo Nọ́ḿbà 23:19 ni o tọ