Nọ́ḿbà 23:3 BMY

3 Nígbà náà Bálámù sọ fún Bálákì pé, “Dúró ní ẹ̀gbẹ́ ẹbọ rẹ kí èmi sì lọ sí ẹ̀gbẹ́ kan. Bóyá Olúwa yóò farahàn mí. Ohunkóhun tí ó bá fihàn, mí màá sọ fún ọ.” Nígbà náà ó sì lọ sí ibi gíga.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 23

Wo Nọ́ḿbà 23:3 ni o tọ