Nọ́ḿbà 23:4 BMY

4 Ọlọ́run sì pàdé rẹ̀, Bálámù sì sọ pé, “Mo tí ṣe pẹpẹ méje, lórí pẹpẹ kọ̀ọ̀kan mo ti fi akọ màlúù àti àgbò kọ̀ọ̀kan rúbọ.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 23

Wo Nọ́ḿbà 23:4 ni o tọ