Nọ́ḿbà 26:65 BMY

65 Nítorí Olúwa ti sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kíkú ni wọn yóò kú sí ihà, kò sì sí ẹnìkankan nínú wọn tí kò kú à fi Kálẹ́bù ọmọ Jéfúnì, àti Jóṣúà ọmọ Núnì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 26

Wo Nọ́ḿbà 26:65 ni o tọ