Nọ́ḿbà 27:1 BMY

1 Ọmọbìnrin Ṣélóféhátì ọmọ Héférì, ọmọ Gílíádì, ọmọ Mákírì ọmọ Mánásè tó jẹ́ ìdílé Mánásè, ọmọ Jósẹ́fù wá. Orúkọ àwọn ọmọbìnrin náà ni Málà, Nóà, Hógílà, Mílíkà àti Tásà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 27

Wo Nọ́ḿbà 27:1 ni o tọ