Nọ́ḿbà 31:20 BMY

20 Kí ẹ̀yin kí ó ya aṣọ yín sí mímọ́ àti gbogbo ohun tí a fi awọ ṣe àti gbogbo iṣẹ́ irun ewúrẹ́ àti ohun tí a fi igi ṣe.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 31

Wo Nọ́ḿbà 31:20 ni o tọ