Nọ́ḿbà 31:21 BMY

21 Élíásárì àlùfáà sì wí fún àwọn olórí ogun náà pé, “Èyí ní ìlànà òfin tí Olúwa fi lélẹ̀ ní àṣẹ fún Mósè.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 31

Wo Nọ́ḿbà 31:21 ni o tọ