Nọ́ḿbà 34:12 BMY

12 Nígbà náà, ààlà náà yóò sọ̀kalẹ̀ lọ sí apá Jọ́dánì, yóò sì dópin nínú Òkun.“ ‘Èyí yóò jẹ́ ilẹ̀ yín, pẹ̀lú ààlà tirẹ̀ ní gbogbo ọ̀nà.’ ”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 34

Wo Nọ́ḿbà 34:12 ni o tọ