Nọ́ḿbà 34:13 BMY

13 Mósè pa á láṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: “Yan ilẹ̀ yìí pẹ̀lú kèké gẹ́gẹ́ bí ìní ogún: Olúwa ti paláṣẹ láti fi fún ẹ̀yà mẹ́san, àti ààbọ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 34

Wo Nọ́ḿbà 34:13 ni o tọ