Nọ́ḿbà 35:15 BMY

15 Ìlú mẹ́fà yìí yóò jẹ́ ìlú ìsásí fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, fún àlejò àti ẹnikẹ́ni tí ó bá ń gbé láàrin wọn, kí ẹnikẹ́ni tí ó bá pa ènìyàn ní àìmọ̀ sá lọ ṣíbẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 35

Wo Nọ́ḿbà 35:15 ni o tọ