Nọ́ḿbà 7:8 BMY

8 O fún àwọn ọmọ Mérárì ní kẹ̀kẹ́ mẹ́rin àti akọ màlúù mẹ́jọ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ wọn ṣe jẹ mọ́. Gbogbo wọn wà lábẹ́ àkóso Ítamárì ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 7

Wo Nọ́ḿbà 7:8 ni o tọ