Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:18 BMY

18 (Júdásì fi èrè àìsòótọ́ rẹ̀ ra ilẹ̀ kan; nígbà tí ó sì subú ni ògèdèǹgbé, ó bẹ́ ní agbede-méjì, gbogbo ifun rẹ̀ sì tú jáde.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:18 ni o tọ