21 Nítorí náà, ó di dandan láti yan ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin wọn tí wọn ti ń bá wa rìn ni gbogbo àkókò tí Jésù Olúwa ń wọlé, tí ó sì jáde láàrin wa.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:21 ni o tọ