Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:2 BMY

2 Olùfọkànsìn, àti ẹni ti ó bẹ̀rù Ọlọ́run tilé tilé rẹ̀ gbogbo, ẹni tí ó ń tọrẹ àánú púpọ̀ fún àwọn ènìyàn, tí ó sì ń gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:2 ni o tọ