21 Nígbà náà ni Pétérù sọ̀kalẹ̀ tọ àwọn ọkùnrin náà tí a rán, ó sì wí pé, “Wò ó, èmi ni ẹni tí ẹ̀yin ń wá: kín ni ìdí tẹ̀ ti ẹ fi wá?”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:21 ni o tọ