37 Ẹ̀yin náà mọ ọ̀rọ̀ náà tí a kéde rẹ̀ yíká gbogbo Jùdíà, tí a bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ láti Gálílì, lẹ́yìn bamitíìsímù ti Jòhánù wàásù rẹ̀.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:37 ni o tọ