39 “Àwa sì ni ẹlẹ́rì gbogbo ohun tí ó ṣe, ní ilẹ̀ àwọn Júù, àti ni Jerúsálémù. Ẹni tí wọ́n pa nípa gbígbékọ́ sí orí igi.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:39 ni o tọ