Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:41 BMY

41 Kì í ṣe fún gbogbo ènìyàn, bí kò ṣe fún àwa ti a jẹ́ ẹlẹ́rìí ti a ti lọ́wọ́ Ọlọ́run yàn tẹ́lé, ti a bá a jẹ, ti a sì bá à mu lẹ́yìn ìgbà ti ó jindé kúrò nínú òkú.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:41 ni o tọ