Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:7 BMY

7 Nígbà tí ańgẹ́lì náà tí ó bá Kọ̀nélíù sọ̀rọ̀ sì fi i sílẹ̀ lọ ó pe méjì nínú àwọn ìránṣẹ́ ilé rẹ̀, ati ọmọ ogun olùfọkànsìn kan, nínú àwọn ti ó máa ń dúró tì í nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:7 ni o tọ