12 Ẹ̀mí sì wí fún mi pé, kí èmi bá wọn lọ, ki èmi má ṣe kọminú ohunkóhun. Àwọn arákùnrin mẹ́fà wọ̀nyí sì bá mi lọ, a sì wọ ilé ọkùnrin náà:
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:12 ni o tọ