28 Nígbà tí ọ̀kan nínú wọn, ti a ń pè ni Ágábù sí dìde, ó ti ipa Ẹ̀mí sọ pé, ìyàn ńlá yóò mú yíká gbogbo ilẹ̀ Róòmù. (Èyí sì ṣẹlẹ̀ nígbà ìsèjọba Kíláúdíù.)
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:28 ni o tọ