Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:11 BMY

11 Nígbà tí ojú Pétérù sì wálẹ̀, ó ní, “Nígbà yìí ni mo tó mọ̀ nítòótọ́ pé, Olúwa rán ańgẹ́lì rẹ̀, ó sì gbà mi lọ́wọ́ Héródù àti gbogbo ohun tí àwọn ènìyàn Júù ń rétí!”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:11 ni o tọ