Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:17 BMY

17 Ṣùgbọ́n ó juwọ́ sí wọn pé kí wọn dákẹ́, ó sì ròyìn fún wọn bí Olúwa ti mú òun jáde kúrò nínú túbú. Ó sì wí pé “Ẹ ro èyí fún Jákọ́bù àti àwọn arákùnrin yòókù!” Ó sì jáde, ó lọ sí ibòmíràn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:17 ni o tọ