Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:15 BMY

15 Lẹ́yìn kíka ìwé òfin àti ìwé àwọn wòlíì, àwọn olórí sínágọ́gù ránṣẹ́ sí wọn, pé, “Ará, bí ẹ̀yin bá ni ọ̀rọ̀ ìyànjú kan fún àwọn ènìyàn, ẹ sọ ọ́!”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:15 ni o tọ