17 Ọlọ́run àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì yìí yan àwọn baba wa, ó sì gbé àwọn ènìyàn náà lékè, nígbà tí wọ́n ṣe àtìpó ní ilẹ̀ Íjíbítì, apá gíga ni ó sì fi mú wọn jáde kúrò nínú rẹ̀,
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:17 ni o tọ