24 Ṣáájú wíwa Jésù ni Jòhánù ti wàásù bamítísímù ìrónúpìwàdà fún gbogbo ènìyàn Isírẹ́lì.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:24 ni o tọ