50 Ṣùgbọ́n àwọn Júù rú àwọn obìnrin olùfọkànsìn àti ọlọ́lá sókè àti àwọn àgbà ìlú náà, wọ́n sì gbé inúnibíni dìde sí Pọ́ọ̀lù àti Básébà, wọ́n sì ṣí wọn kúrò ni agbégbé wọn.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:50 ni o tọ