Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:7 BMY

7 Ó wà lọ́dọ̀ Ségíù Páúlúsì baálẹ̀ ìlú náà, amòye ènìyàn. Òun náà ni ó ránṣẹ́ pe Bánábà àti Ṣọ́ọ̀lù, nítorí tí ó fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:7 ni o tọ