Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:19 BMY

19 Àwọn Júù kan sì ti Áńtíókù àti Ìkóníónì wá, nígbà tí wọ́n yí àwọn ènìyàn lọ́kan padà, wọ́n sì sọ Pọ́ọ̀lù ní òkúta, wọ́n wọ́ ọ kúrò sí ẹ̀yin odi ìlú náà, wọn ṣèbí ó kú.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:19 ni o tọ