Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:21 BMY

21 Nígbà tí wọ́n sì ti wàásù ìyìn rere fún ìlú náà, tí wọ́n sì ni ọmọ-ẹ̀yìn púpọ̀, wọn padà lọ sí Lísírà, àti Ikóníónì, àti Áńtíókù,

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:21 ni o tọ