Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:23 BMY

23 Nígbà tí wọ́n sì ti yan àwọn alàgbà fún olúkúlùkù ìjọ, tí wọn sì ti fi àwẹ̀ gbàdúrà, wọn fi à wọ́n lé ẹni gbàgbọ́ Olúwa lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:23 ni o tọ