Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:1 BMY

1 ÀWỌN ọkùnrin kan tí Jùdíà sọ̀kalẹ̀ wá, wọ́n sì kọ́ àwọn arakùnrin pé, “Bí kò ṣe pé a bá kọ yín ni ilà bí ìṣe Mósè, ẹ̀yin kí yóò lè là.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:1 ni o tọ