Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:29 BMY

29 Kí ẹ̀yin fà sẹ̀yìn kúrò nínú ẹran àpabọ òrìṣà, àti nínú ẹ̀jẹ̀ àti nínú ohun ìlọ́lọ́rùn-pa, àti nínú àgbérè: nínú ohun tí, bí ẹ̀yin bá pa ara yín mọ́ kúrò, ẹ̀yin ó ṣe rere.Àlàáfíà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:29 ni o tọ