Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:3 BMY

3 Nítorí náà, bí ìjọ ti rán wọn jáde lọ sí ọ̀nà wọn, wọn la Féníkè àti Samaríà kọjá, wọ́n ń ròyìn ìyípadà àwọn aláìkọlà: wọ́n sì fi ayọ̀ ńlá fún gbogbo àwọn arákùnrin.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:3 ni o tọ