31 Wọ́n sì wí fún un pé, “Gbá Jéṣù Kírísítì Olúwa gbọ́, a ó sì gbà ọ́ là, ìwọ àti àwọn ará ilé rẹ pẹ̀lú.”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:31 ni o tọ